Fò sí àkóónú
Deuteronomi 23:7-8

Ìgbàwọlé àwọn ará Édómù àti àwọn ará Íjíbítì

Deuteronomi 23:7-8
7
Ìwọ kò gbọdọ̀ kórìíra ará Edomu kan nítorí arákùnrin rẹ ni. Ìwọ kò gbọdọ̀ kórìíra ará Ejibiti, nítorí o gbé gẹ́gẹ́ bí àjèjì ní ilẹ̀ rẹ̀.
8
Ìran kẹta àwọn ọmọ tí a bí fún wọn lè wọ ìpéjọ Olúwa.
Settings

Reading Style

Typeface

Font Size 19px

Reading Width 45 chars

Options