Skip to content
1 Ọba 14:19-20

Àkótán ìṣàkóso Jeroboamu

1 Ọba 14:19-20
19
Ìyókù ìṣe Jeroboamu, bí ó ti jagun, àti bí ó ti jẹ ọba, ni a kọ sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba Israẹli.
20
Jeroboamu sì jẹ ọba fún ọdún méjìlélógún, ó sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. Nadabu ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
Settings

Reading style

Typeface

Font size 19px

Reading width 90 chars

Options