1 Kronika 1:20-23
20
Joktani sì bí Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera.
21
Hadoramu, Usali, Dikla,
22
Ebali, Abimaeli, Ṣeba.
23
Ofiri, Hafila, àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani.
Ọ̀rọ̀ Bíbélì: Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™, © 2009, 2017 Biblica, Inc. · CC BY-SA 4.0“Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc., used with permission.