Joṣua 15:63
Ń ṣàfihàn ẹsẹ 63 pẹ̀lú àyíká ọ̀rọ̀ tó yí i ká.
60
Kiriati-Baali (tí í ṣe, Kiriati-Jearimu) àti Rabba ìlú méjì àti ìletò wọn.
61
Ní aginjù: Beti-Araba, Middini, Sekaka,
62
Nibṣani, Ìlú Iyọ̀ àti En-Gedi: ìlú mẹ́fà àti ìletò wọn.
63
Juda kò lè lé àwọn ọmọ Jebusi jáde, tí wọ́n ń gbé ní Jerusalẹmu. Àwọn ará Jebusi sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn Juda títí dí òní.
Settings